Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kọrinti Kinni 9:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Tabi kò dájú pé nítorí tiwa ni ó ṣe sọ ọ́? Dájúdájú nítorí tiwa ni. Nítorí ó yẹ kí ẹni tí ń roko kí ó máa roko pẹlu ìrètí láti pín ninu ìkórè oko, bẹ́ẹ̀ ni kí ẹni tí ó ń pa ọkà ní ìrètí láti pín ninu ọkà náà.

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 9

Wo Kọrinti Kinni 9:10 ni o tọ