Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kọrinti Kinni 8:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí bí ẹnìkan tí ẹ̀rí-ọkàn rẹ̀ kò bá lágbára bá rí ìwọ tí o ní ìmọ̀ tí ò ń jẹun ní ilé oriṣa, ǹjẹ́ òun náà kò ní fi ìgboyà wọ inú ilé oriṣa lọ jẹun?

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 8

Wo Kọrinti Kinni 8:10 ni o tọ