Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kọrinti Kinni 7:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ohun tí ìbá wù mí fun yín ni pé kí gbogbo eniyan rí bí mo ti rí; ṣugbọn ẹ̀bùn tí Ọlọrun fún olukuluku yàtọ̀, ó fún àwọn kan ní oríṣìí kan, ó fún àwọn mìíràn ní oríṣìí mìíràn.

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 7

Wo Kọrinti Kinni 7:7 ni o tọ