Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kọrinti Kinni 6:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Nǹkankan kù díẹ̀ kí ó tó nípa igbagbọ yín. Òun ni ó mú kí ẹ máa ní ẹ̀sùn sí ara yín. Kí ni kò jẹ́ kí olukuluku yín kúkú máa gba ìwọ̀sí? Kí ni kò jẹ́ kí ẹ máa gba ìrẹ́jẹ?

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 6

Wo Kọrinti Kinni 6:7 ni o tọ