Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kọrinti Kinni 6:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Àbí ẹ kò mọ̀ pé àwọn onigbagbọ ni yóo ṣe ìdájọ́ ayé? Nígbà tí ó jẹ́ pé ẹ̀yin ni ẹ óo ṣe ìdájọ́ ayé, ó ti wá jẹ́ tí ẹ kò fi lè ṣe ìdájọ́ àwọn tí ó kéré jùlọ?

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 6

Wo Kọrinti Kinni 6:2 ni o tọ