Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kọrinti Kinni 6:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn mìíràn wà ninu yín tí wọn ń hu irú ìwà báyìí tẹ́lẹ̀. Ṣugbọn nisinsinyii, a ti wẹ̀ yín mọ́, a ti yà yín sọ́tọ̀, a ti da yín láre nípa orúkọ Oluwa Jesu Kristi ati nípa Ẹ̀mí Ọlọrun wa.

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 6

Wo Kọrinti Kinni 6:11 ni o tọ