Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kọrinti Kinni 5:12-13 BIBELI MIMỌ (BM)

Èwo ni tèmi láti dá alaigbagbọ lẹ́jọ́? Ṣebí àwọn onigbagbọ ara yín ni ẹ̀ ń dá lẹ́jọ́? Ọlọrun ni ó ń ṣe ìdájọ́ àwọn alaigbagbọ. Ẹ yọ ẹni burúkú náà kúrò láàrin yín.

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 5

Wo Kọrinti Kinni 5:12-13 ni o tọ