Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kọrinti Kinni 2:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Gẹ́gẹ́ bí ó ti wà ní àkọsílẹ̀ pé,“Ohun tí ojú kò ì tíì rí, tí etí kò ì tíì gbọ́,Ohun tí kò wá sí ọkàn ẹ̀dá kan rí,ni ohun tí Ọlọrun ti pèsè sílẹ̀ fún àwọn àyànfẹ́ rẹ̀.”

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 2

Wo Kọrinti Kinni 2:9 ni o tọ