Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kọrinti Kinni 2:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn à ń sọ̀rọ̀ ọgbọ́n Ọlọrun, ohun àṣírí tí ó ti wà ní ìpamọ́, tí Ọlọrun ti ṣe ètò sílẹ̀ láti ìṣẹ̀dálẹ̀ ayé fún ògo wa.

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 2

Wo Kọrinti Kinni 2:7 ni o tọ