Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kọrinti Kinni 2:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí ẹ̀dá alààyè wo ni ó mọ ohun tí ó wà ninu eniyan kan bíkòṣe ẹ̀mí olúwarẹ̀ tí ó wà ninu rẹ̀? Bẹ́ẹ̀ gan-an ni àwọn nǹkan Ọlọrun: kò sí ẹni tí ó mọ̀ wọ́n àfi Ẹ̀mí Ọlọrun.

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 2

Wo Kọrinti Kinni 2:11 ni o tọ