Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kọrinti Kinni 16:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Nípa ti arakunrin wa Apolo, mo gbà á níyànjú gidigidi pé kí ó wá sọ́dọ̀ yín pẹlu àwọn arakunrin yòókù. Ṣugbọn ó pinnu pé òun kò fẹ́ wá ní àkókò yìí. Ó ń bọ̀ nígbà tí ó bá yá.

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 16

Wo Kọrinti Kinni 16:12 ni o tọ