Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kọrinti Kinni 15:48 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ẹni tí a fi erùpẹ̀ dá ti rí, bẹ́ẹ̀ ni gbogbo àwọn tí a fi erùpẹ̀ dá rí. Bí ẹni tí ó wá láti ọ̀run ti rí, bẹ́ẹ̀ ni gbogbo àwọn ti ọ̀run rí.

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 15

Wo Kọrinti Kinni 15:48 ni o tọ