Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kọrinti Kinni 14:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí kò bá sí ẹni tí yóo ṣe ìtumọ̀, kí ẹni tí ó fẹ́ fi èdè àjèjì sọ̀rọ̀ dákẹ́ ninu ìjọ. Kí ó máa fi èdè àjèjì bá ara rẹ̀ ati Ọlọrun sọ̀rọ̀.

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 14

Wo Kọrinti Kinni 14:28 ni o tọ