Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kọrinti Kinni 14:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ohun ìkọ̀kọ̀ ọkàn rẹ̀ yóo hàn kedere, ni yóo bá dojúbolẹ̀, yóo sì júbà Ọlọrun. Yóo sọ pé, “Dájúdájú Ọlọrun wà láàrin yín.”

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 14

Wo Kọrinti Kinni 14:25 ni o tọ