Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kọrinti Kinni 11:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Bákan náà ni ó mú ife lẹ́yìn oúnjẹ, ó ní, “Èyí ni ife ti majẹmu titun tí a fi ẹ̀jẹ̀ mi dá. Nígbàkúùgbà tí ẹ bá ń mu ún, ẹ máa ṣe èyí ní ìrántí mi.”

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 11

Wo Kọrinti Kinni 11:25 ni o tọ