Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kọrinti Kinni 10:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Lóòótọ́, “Ohun tí a bá fẹ́ ni a lè ṣe,” bí àwọn kan ti ń wí. Ṣugbọn kì í ṣe gbogbo nǹkan ni ó ń ṣe eniyan ní anfaani. “Ohun tí a bá fẹ́ ni a lè ṣe.” Ṣugbọn kì í ṣe gbogbo nǹkan tí a lè ṣe ni ó ń mú ìdàgbà wá.

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 10

Wo Kọrinti Kinni 10:23 ni o tọ