Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kọrinti Kinni 1:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Nípa iṣẹ́ Ọlọrun, ẹ̀yin wà ní ìṣọ̀kan pẹlu Kristi Jesu. Òun ni Ọlọrun fi ṣe ọgbọ́n wa ati òdodo wa. Òun ni ó sọ wá di mímọ́, tí ó dá wa nídè.

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 1

Wo Kọrinti Kinni 1:30 ni o tọ