Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kọrinti Kinni 1:23 BIBELI MIMỌ (BM)

ṣugbọn ní tiwa, àwa ń waasu Kristi tí wọ́n kàn mọ́ agbelebu. Ohun ìkọsẹ̀ ni iwaasu wa yìí jẹ́ lójú àwọn Juu, ọ̀rọ̀ òmùgọ̀ sì ni lójú àwọn orílẹ̀-èdè yòókù;

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 1

Wo Kọrinti Kinni 1:23 ni o tọ