Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kọrinti Kinni 1:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Sí ìjọ Ọlọrun ti ó wà ní Kọrinti, àwọn tí a yà sí mímọ́ nípa ìṣọ̀kan pẹlu Kristi Jesu, tí a pè láti jẹ́ eniyan ọ̀tọ̀, ati gbogbo àwọn tí ń pe orúkọ Oluwa wa Jesu Kristi níbi gbogbo, Jesu tíí ṣe Oluwa tiwọn ati tiwa.

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 1

Wo Kọrinti Kinni 1:2 ni o tọ