Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kọrinti Kinni 1:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí ọ̀rọ̀ agbelebu Kristi jẹ́ ọ̀rọ̀ òmùgọ̀ lójú àwọn tí ń ṣègbé. Ṣugbọn lójú àwọn tí à ń gbà là, agbára Ọlọrun ni.

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 1

Wo Kọrinti Kinni 1:18 ni o tọ