Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kọrinti Kinni 1:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀yin ará, mo fi orúkọ Oluwa wa Jesu Kristi bẹ̀ yín, gbogbo yín, ẹ fohùn ṣọ̀kan, kí ó má sí ìyapa láàrin yín. Ẹ jẹ́ kí ọkàn yín ṣe ọ̀kan, kí èrò yín sì papọ̀.

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 1

Wo Kọrinti Kinni 1:10 ni o tọ