Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kọrinti Keji 9:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, mo rí i pé ó di dandan pé kí n bẹ àwọn arakunrin láti ṣiwaju mi wá sọ́dọ̀ yín, kí wọ́n ṣe ètò sílẹ̀ nípa ẹ̀bùn tí ẹ ti ṣe ìlérí, kí ó jẹ́ pé yóo ti wà nílẹ̀ kí n tó dé. Èyí yóo mú kí ó jẹ́ ọrẹ àtinúwá, kò ní jẹ́ ti ìlọ́ni-lọ́wọ́-gbà.

Ka pipe ipin Kọrinti Keji 9

Wo Kọrinti Keji 9:5 ni o tọ