Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kọrinti Keji 8:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí nígbà tí a sọ pé kí ó wá sọ́dọ̀ yín, pẹlu ayọ̀ ni ó fi gbà láti wá. Òun fúnrarẹ̀ tilẹ̀ ní àníyàn láti wá sọ́dọ̀ yín tẹ́lẹ̀.

Ka pipe ipin Kọrinti Keji 8

Wo Kọrinti Keji 8:17 ni o tọ