Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kọrinti Keji 8:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Èrò mi lórí ọ̀rọ̀ yìí ni pé ohun tí ó dára jùlọ fun yín ni. Nígbà tí kì í tíí ṣe pé ẹ ti ń ṣe é nìkan ni, ṣugbọn tìfẹ́tìfẹ́ ni ẹ ti fi ń ṣe é láti ọdún tí ó kọjá,

Ka pipe ipin Kọrinti Keji 8

Wo Kọrinti Keji 8:10 ni o tọ