Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kọrinti Keji 7:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Kì í ṣe pé mò ń fi èyí ba yín wí. Nítorí, bí mo ti sọ ṣáájú, ẹ ṣe ọ̀wọ́n fún wa tóbẹ́ẹ̀ tí ó fi jẹ́ pé bí ó bá kan ti ikú, kí á jọ kú ni, bí ó bá sì jẹ́ ti ìyè, kí á jọ wà láàyè ni.

Ka pipe ipin Kọrinti Keji 7

Wo Kọrinti Keji 7:3 ni o tọ