Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kọrinti Keji 7:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí mo kọ ìwé tí mo kọ́ kọ, kì í ṣe nítorí ti ẹni tí ó ṣe àìdára, bẹ́ẹ̀ ni kì í ṣe nítorí ti ẹni tí wọ́n ṣe àìdára sí. Ṣugbọn mo kọ ọ́ kí ìtara yín lè túbọ̀ hàn níwájú Ọlọrun.

Ka pipe ipin Kọrinti Keji 7

Wo Kọrinti Keji 7:12 ni o tọ