Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kọrinti Keji 6:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí ni oriṣa ń wá ninu ilé Ọlọrun? Nítorí ilé Ọlọrun alààyè ni àwa jẹ́. Gẹ́gẹ́ bí Ọlọrun ti sọ, pé,“N óo máa gbé ààrin wọn,n óo máa káàkiri ní ààrin wọn.N óo jẹ́ Ọlọrun wọn,wọn yóo sì jẹ́ eniyan mi.

Ka pipe ipin Kọrinti Keji 6

Wo Kọrinti Keji 6:16 ni o tọ