Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kọrinti Keji 4:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn oriṣa ayé yìí ni wọ́n fọ́ irú àwọn ẹni bẹ́ẹ̀ lójú, tí ọkàn wọn kò fi lè gbàgbọ́. Èyí ni kò jẹ́ kí ìmọ́lẹ̀ ìyìn rere Kristi, tí ó lógo, kí ó tàn sí wọn lára; àní, Kristi tíí ṣe àwòrán Ọlọrun.

Ka pipe ipin Kọrinti Keji 4

Wo Kọrinti Keji 4:4 ni o tọ