Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kọrinti Keji 4:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Kì í ṣe àwọn nǹkan tí a lè fi ojú rí ni a tẹjúmọ́, bíkòṣe àwọn nǹkan tí a kò lè fi ojú rí. Nítorí àwọn nǹkan tí yóo wà fún ìgbà díẹ̀ ni àwọn nǹkan tí a lè fi ojú rí. Àwọn nǹkan tí a kò lè fi ojú rí ni yóo wà títí laelae.

Ka pipe ipin Kọrinti Keji 4

Wo Kọrinti Keji 4:18 ni o tọ