Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kọrinti Keji 4:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà ni a kò fi sọ ìrètí nù. Nítorí pé, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ara wa ti òde ń bàjẹ́, ṣugbọn ara wa ti inú ń di titun sí i lojoojumọ.

Ka pipe ipin Kọrinti Keji 4

Wo Kọrinti Keji 4:16 ni o tọ