Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kọrinti Keji 3:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó hàn gbangba pé ẹ̀yin ni ìwé tí Kristi kọ, tí ó fi rán wa. Kì í ṣe irú èyí tí wọ́n fi yíǹkì kọ, Ẹ̀mí Ọlọrun alààyè ni wọ́n fi kọ ọ́. Kì í ṣe èyí tí wọ́n kọ sí orí òkúta; ọkàn eniyan ni wọ́n kọ ọ́ sí.

Ka pipe ipin Kọrinti Keji 3

Wo Kọrinti Keji 3:3 ni o tọ