Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kọrinti Keji 12:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn àmì aposteli hàn ninu iṣẹ́ mi láàrin yín nípa oríṣìíríṣìí ìfaradà, nípa iṣẹ́ abàmì, iṣẹ́ ìyanu, ati iṣẹ́ agbára.

Ka pipe ipin Kọrinti Keji 12

Wo Kọrinti Keji 12:12 ni o tọ