Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kọrinti Keji 1:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí Jesu Kristi, Ọmọ Ọlọrun, tí èmi, Silifanu ati Timoti, ń waasu rẹ̀ fun yín, kì í ṣe “bẹ́ẹ̀ ni” ati “bẹ́ẹ̀ kọ́”. Ṣugbọn “bẹ́ẹ̀ ni” ni tirẹ̀.

Ka pipe ipin Kọrinti Keji 1

Wo Kọrinti Keji 1:19 ni o tọ