Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kọrinti Keji 1:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Èmi Paulu, aposteli Kristi Jesu nípasẹ̀ ìfẹ́ Ọlọrun, ati Timoti, arakunrin wa, ni à ń kọ ìwé yìí sí Ìjọ Ọlọrun tí ó wà ní Kọrinti ati sí gbogbo àwọn eniyan Ọlọrun tí ó wà ní Akaya.

Ka pipe ipin Kọrinti Keji 1

Wo Kọrinti Keji 1:1 ni o tọ