Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kolose 3:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ ní ìfaradà láàrin ara yín. Ẹ máa dáríjì ara yín bí ẹnikẹ́ni bá ní ẹ̀sùn kan sí ẹnìkejì rẹ̀; gẹ́gẹ́ bí Oluwa ti dáríjì yín bẹ́ẹ̀ gan-an ni kí ẹ̀yin náà máa ṣe sí ara yín.

Ka pipe ipin Kolose 3

Wo Kolose 3:13 ni o tọ