Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kolose 2:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìdí akitiyan mi ni pé kí Ọlọrun lè mu yín ní ọkàn le, kí ó so yín pọ̀ ninu ìfẹ́ ati ọrọ̀ òye tí ó dájú, kí ẹ sì ní ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ àṣírí Ọlọrun, tíí ṣe Kristi fúnrarẹ̀.

Ka pipe ipin Kolose 2

Wo Kolose 2:2 ni o tọ