Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kolose 1:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìyìn rere yìí ti dé ọ̀dọ̀ yín gẹ́gẹ́ bí ó ti dé ọ̀dọ̀ gbogbo aráyé, ó ń so èso, ó sì ń dàgbà. Bẹ́ẹ̀ ni ó sì rí láàrin ẹ̀yin náà láti ọjọ́ tí ẹ ti gbọ́, tí ẹ sì ti mọ oore-ọ̀fẹ́ Ọlọrun nítòótọ́.

Ka pipe ipin Kolose 1

Wo Kolose 1:6 ni o tọ