Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kolose 1:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Nípa rẹ̀ ni Ọlọrun ṣe gbogbo nǹkan lọ́kan pẹlu ara rẹ̀, kí alaafia lè dé nípa ikú rẹ̀ lórí agbelebu. Gbogbo nǹkan wá wà ní ìṣọ̀kan, ìbáà ṣe nǹkan ti ayé tabi àwọn nǹkan ti ọ̀run.

Ka pipe ipin Kolose 1

Wo Kolose 1:20 ni o tọ