Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kolose 1:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Sí ìjọ eniyan Ọlọrun tí ó wà ní Kolose, sí àwọn arakunrin tí ó jẹ́ olóòótọ́ sí Kristi.Kí oore-ọ̀fẹ́ ati alaafia láti ọ̀dọ̀ Ọlọrun Baba wa kí ó wà pẹlu yín.

Ka pipe ipin Kolose 1

Wo Kolose 1:2 ni o tọ