Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kolose 1:11-12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ati pé kí Ọlọrun fun yín ní agbára gẹ́gẹ́ bí ọ̀pọ̀ ògo rẹ̀, kí ó fun yín ní ìfaradà ninu ohun gbogbo, pẹlu sùúrù ati ayọ̀. Kí ẹ máa dúpẹ́ lọ́wọ́ Baba wa tí ó kà yín yẹ láti ní ìpín ninu ogún àwọn eniyan Ọlọrun ninu ìmọ́lẹ̀.

Ka pipe ipin Kolose 1

Wo Kolose 1:11-12 ni o tọ