Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Juda 1:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Bẹ́ẹ̀ náà ni ó rí fún àwọn eniyan wọnyi lónìí. Àlá tí wọn ń lá, fún ìbàjẹ́ ara wọn ni. Wọ́n tàpá sí àwọn aláṣẹ. Wọ́n ń sọ ìsọkúsọ sí àwọn ẹ̀dá ọ̀run tí ó lógo.

Ka pipe ipin Juda 1

Wo Juda 1:8 ni o tọ