Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Johanu 9:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àwọn aládùúgbò rẹ̀ ati àwọn tí wọn máa ń rí i tẹ́lẹ̀ tí ó máa ń ṣagbe, rí i, wọ́n ń bi ara wọn pé, “Ǹjẹ́ ọkunrin yìí kọ́ ni ó ti máa ń jókòó, tí ó máa ń ṣagbe rí?”

Ka pipe ipin Johanu 9

Wo Johanu 9:8 ni o tọ