Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Johanu 8:52 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn Juu wá sọ fún un pé, “A wá mọ̀ dájú pé o ní ẹ̀mí èṣù wàyí! Abrahamu kú. Àwọn wolii kú. Ìwọ wá ń sọ pé, ‘Bí ẹnikẹ́ni bá pa ọ̀rọ̀ mi mọ́, kò ní tọ́ ikú wò laelae.’

Ka pipe ipin Johanu 8

Wo Johanu 8:52 ni o tọ