Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Johanu 8:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn amòfin ati àwọn Farisi mú obinrin kan wá, tí wọ́n ká mọ́ ibi tí ó ti ń ṣe àgbèrè. Wọ́n ní kí ó dúró láàrin wọn;

Ka pipe ipin Johanu 8

Wo Johanu 8:3 ni o tọ