Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Johanu 8:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí mo bá tilẹ̀ ṣe ìdájọ́, òtítọ́ ni ìdájọ́ mi, nítorí kì í ṣe èmi nìkan ni mò ń ṣe ìdájọ́, èmi ati Baba tí ó rán mi níṣẹ́ ni.

Ka pipe ipin Johanu 8

Wo Johanu 8:16 ni o tọ