Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Johanu 7:32 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn Farisi gbọ́ pé àwọn eniyan ń sọ ọ̀rọ̀ kẹ́lẹ́kẹ́lẹ́ báyìí láàrin ara wọn nípa Jesu. Àwọn olórí alufaa ati àwọn Farisi wá rán àwọn ẹ̀ṣọ́ Tẹmpili pé kí wọ́n lọ mú Jesu wá.

Ka pipe ipin Johanu 7

Wo Johanu 7:32 ni o tọ