Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Johanu 7:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹni tí ó bá ń sọ̀rọ̀ ti ara rẹ̀ ń wá ògo ti ara rẹ̀. Ṣugbọn ẹni tí ó bá ń wá ògo ẹni tí ó rán an níṣẹ́ jẹ́ olóòótọ́, kò sí aiṣododo ninu rẹ̀.

Ka pipe ipin Johanu 7

Wo Johanu 7:18 ni o tọ