Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Johanu 6:39 BIBELI MIMỌ (BM)

Èyí ni ìfẹ́ ẹni tí ó rán mi níṣẹ́, pé kí n má ṣe sọ ẹnikẹ́ni nù ninu àwọn tí ó fi fún mi, ṣugbọn kí n jí wọn dìde ní ọjọ́ ìkẹyìn.

Ka pipe ipin Johanu 6

Wo Johanu 6:39 ni o tọ