Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Johanu 6:35 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesu dá wọn lóhùn pé, “Èmi gan-an ni oúnjẹ tí ń fún eniyan ní ìyè, ẹni tí ó bá wá sọ́dọ̀ mi, ebi kò ní pa á, ẹni tí ó bá sì gbà mí gbọ́, òùngbẹ kò ní gbẹ ẹ́ laelae.

Ka pipe ipin Johanu 6

Wo Johanu 6:35 ni o tọ