Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Johanu 6:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn tí wọ́n ti wa ọkọ̀ bí ibùsọ̀ mẹta tabi mẹrin wọ́n rí Jesu, ó ń rìn lórí òkun, ó ti súnmọ́ etí ọkọ̀ wọn. Ẹ̀rù bà wọ́n.

Ka pipe ipin Johanu 6

Wo Johanu 6:19 ni o tọ